Samuel L. Jackson
| Samuel L. Jackson | |
|---|---|
Jackson ní ọdún 2022 | |
| Ọjọ́ìbí | Samuel Leroy Jackson 21 Oṣù Kejìlá 1948 Washington, D.C., U.S. |
| Ọmọ orílẹ̀-èdè |
|
| Ẹ̀kọ́ | Morehouse College (BA) |
| Iṣẹ́ |
|
| Ìgbà iṣẹ́ | 1972–present |
| Works | Full list |
| Olólùfẹ́ | |
| Àwọn ọmọ | 1 |
| Awards | Full list |
Samuel Leroy Jackson (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù Kejìlá ọdún 1948) jẹ́ òṣèré ọmọ orilẹ̀-èdè actor Amerika. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèré tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní ìran rẹ̀ a, àwọn fíìmù tí ó ti ṣeré ti pa iye owó tí ó lé ní bílíọ́nù mẹ́tàdínlógún dọ́là ($27 billion), èyí mú kí ó jẹ́ òṣèré kejì tí àwọn eré rẹ̀ ti pa owó jù.[lower-alpha 1]. Ní ọdún 2022, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Honorary Award.[4][5][6]
Jackson bẹ̀rẹ̀ isẹ́ òṣèré perewu ní ọdún 1980 nígbà tí ó ṣeré nínú Mother Courage and her Children ní The Public Theatre. Láàrin ọdún 1981 sí ọdún 1983, ó ṣeré A Soldier's Play off-Broadway. Ó tún ṣeré nínú fíìmù The Piano Lesson ní ọdún 1987 ní Yale Repertory Theatre. Ó kópa Martin Luther King Jr. nínú fíìmù The Mountaintop (2011).[7]
Àwọn eré tí Jackson kọ́kọ́ ṣe ni Coming to America (1988), Juice (1992), True Romance (1993), Menace II Society (1993), àti Fresh (1994).
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Box Office Mojo – People Index". Box Office Mojo. Archived from the original on June 27, 2019. Retrieved October 17, 2019. Unknown parameter
|url-status=ignored (help) - ↑ Powers, Lindsay (October 27, 2011). "Samuel L. Jackson Is Highest-Grossing Actor of All Time". The Hollywood Reporter. https://www.hollywoodreporter.com/news/samuel-l-jackson-highest-grossing-actor-guinness-book-world-records-254155/.
- ↑ "Samuel L. Jackson Movie Box Office Results".